Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 4:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti a nṣe lãlã, a nfi ọwọ́ ara wa ṣiṣẹ: nwọn ngàn wa, awa nsure; nwọn nṣe inunibini si wa, awa nforitì i:

Ka pipe ipin 1. Kor 4

Wo 1. Kor 4:12 ni o tọ