Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 25:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe, o san ki a wi fun ọ pe, wá soke nihin, jù ki a fà ọ tì sẹhin niwaju ọmọ-alade ti oju rẹ ti ri.

Ka pipe ipin Owe 25

Wo Owe 25:7 ni o tọ