Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 25:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. WỌNYI pẹlu li owe Solomoni, ti awọn ọkunrin Hesekiah, ọba Judah kọ silẹ.

2. Ogo Ọlọrun ni lati pa ọ̀ran mọ́: ṣugbọn ọlá awọn ọba ni lati wadi ọ̀ran.

Ka pipe ipin Owe 25