Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 85:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o gbọ́ bi Ọlọrun Oluwa yio ti wi: nitoriti yio sọ alafia si awọn enia rẹ̀, ati si awọn enia mimọ́ rẹ̀: ṣugbọn ki nwọn ki o má tun pada si were.

Ka pipe ipin O. Daf 85

Wo O. Daf 85:8 ni o tọ