Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 76:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

A kó awọn alaiya lile ni ikogun, nwọn ti sùn orun wọn, gbogbo ọkunrin alagbara kò si ri ọwọ wọn.

Ka pipe ipin O. Daf 76

Wo O. Daf 76:5 ni o tọ