Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 69:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun, máṣe jẹ ki oju ki o tì awọn ti o duro de ọ nitori mi: máṣe jẹ ki awọn ti nwá ọ ki o damu nitori mi, Ọlọrun Israeli.

Ka pipe ipin O. Daf 69

Wo O. Daf 69:6 ni o tọ