Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 63:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ỌLỌRUN, iwọ li Ọlọrun mi; ni kutukutu li emi o ma ṣafẹri rẹ; ongbẹ rẹ ngbẹ ọkàn mi, ẹran-ara mi fà si ọ ni ilẹ gbigbẹ, ati ilẹ ti npongbẹ, nibiti omi kò gbe si.

Ka pipe ipin O. Daf 63

Wo O. Daf 63:1 ni o tọ