Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 27:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbayi li ori mi yio gbé soke ga jù awọn ọta mi lọ, ti o yi mi ká, nitorina li emi o ṣe rubọ ayọ̀ ninu agọ rẹ̀; emi o kọrin, nitõtọ emi o kọrin iyìn si Oluwa.

Ka pipe ipin O. Daf 27

Wo O. Daf 27:6 ni o tọ