Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 139:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi emi ba gòke lọ si ọrun, iwọ wà nibẹ: bi emi ba si tẹ́ ẹni mi ni ipò okú, kiyesi i, iwọ wà nibẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 139

Wo O. Daf 139:8 ni o tọ