Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 126:1-4 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBATI Oluwa mu ikólọ Sioni pada, awa dabi ẹniti nla alá.

2. Nigbana li ẹnu wa kún fun ẹrin, ati ahọn wa kọ orin: nigbana ni nwọn wi ninu awọn keferi pe, Oluwa ṣe ohun nla fun wọn.

3. Oluwa ṣe ohun nla fun wa: nitorina awa nyọ̀.

4. Oluwa mu ikólọ wa pada, bi iṣan-omi ni gusu.

Ka pipe ipin O. Daf 126