Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 126:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ẹnu wa kún fun ẹrin, ati ahọn wa kọ orin: nigbana ni nwọn wi ninu awọn keferi pe, Oluwa ṣe ohun nla fun wọn.

Ka pipe ipin O. Daf 126

Wo O. Daf 126:2 ni o tọ