Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 35:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin kò si gbọdọ bà ilẹ na jẹ́ ninu eyiti ẹnyin ngbé: nitoripe ẹ̀jẹ ama bà ilẹ jẹ́: a kò si le ṣètutu fun ilẹ nitori ẹ̀je ti a ta sinu rẹ̀, bikoṣe nipa ẹ̀jẹ ẹniti o ta a.

Ka pipe ipin Num 35

Wo Num 35:33 ni o tọ