Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 33:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si ṣí kuro niwaju Hahirotu, nwọn si là ãrin okun já lọ si aginjù: nwọn si rìn ìrin ijọ́ mẹta li aginjù Etamu, nwọn si dó si Mara.

Ka pipe ipin Num 33

Wo Num 33:8 ni o tọ