Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 33:55 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi ẹnyin kò ba lé awọn ara ilẹ na kuro niwaju nyin; yio si ṣe, awọn ti ẹnyin jẹ ki o kù ninu wọn yio di ẹgún si oju nyin, ati ẹgún si nyin ni ìha, nwọn o si ma yọ nyin lẹnu ni ilẹ na, ninu eyiti ẹnyin ngbé.

Ka pipe ipin Num 33

Wo Num 33:55 ni o tọ