Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 33:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si ṣí kuro ni Ramesesi li oṣù kini, ni ijọ́ kẹdogun oṣù kini na; ni ijọ́ keji ajọ irekọja li awọn ọmọ Israeli jade pẹlu ọwọ́ giga li oju gbogbo awọn ara Egipti.

Ka pipe ipin Num 33

Wo Num 33:3 ni o tọ