Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 33:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si kọwe ijadelọ wọn gẹgẹ bi ìrin wọn, nipa aṣẹ OLUWA; wọnyi si ni ìrin wọn gẹgẹ bi ijadelọ wọn.

Ka pipe ipin Num 33

Wo Num 33:2 ni o tọ