Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 32:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti a o si fi ṣẹ́ ilẹ na niwaju OLUWA: lẹhin na li ẹnyin o pada, ẹnyin o si jẹ́ àlailẹṣẹ niwaju OLUWA, ati niwaju Israeli; ilẹ yi yio si ma jẹ́ iní nyin niwaju OLUWA.

Ka pipe ipin Num 32

Wo Num 32:22 ni o tọ