Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 3:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti a kà ninu awọn ọmọ Lefi, ti Mose ati Aaroni kà nipa aṣẹ OLUWA, gẹgẹ bi idile wọn, gbogbo awọn ọkunrin lati ọmọ oṣù kan lọ ati jù bẹ̃ lọ, nwọn jẹ́ ẹgba mọkanla,

Ka pipe ipin Num 3

Wo Num 3:39 ni o tọ