Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 28:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọdọ-agutan keji ni ki iwọ ki o fi rubọ li aṣalẹ: bi ẹbọ ohunjijẹ ti owurọ̀, ati bi ẹbọ ohunmimu rẹ̀ ni ki iwọ ki o ṣe, ẹbọ ti a fi iná ṣe, õrùn didùn si OLUWA.

Ka pipe ipin Num 28

Wo Num 28:8 ni o tọ