Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 28:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o si wi fun wọn pe, Eyi li ẹbọ ti a fi iná ṣe, ti ẹnyin o ma múwa fun OLUWA, akọ ọdọ-agutan meji ọlọdún kan alailabùku li ojojumọ́, fun ẹbọ sisun igbagbogbo.

Ka pipe ipin Num 28

Wo Num 28:3 ni o tọ