Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 28:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹbọ ohunmimu wọn ki o jẹ́ àbọ òṣuwọn hini ti ọti-waini fun akọmalu kan, ati idamẹta òṣuwọn hini fun àgbo kan, ati idamẹrin òṣuwọn hini fun ọdọ-agutan kan: eyi li ẹbọ sisun oṣuṣù ni gbogbo oṣù ọdún.

Ka pipe ipin Num 28

Wo Num 28:14 ni o tọ