Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 26:54 Yorùbá Bibeli (YCE)

Fun awọn ti o pọ̀ ni ki iwọ ki o fi ilẹ-iní pupọ̀ fun, ati fun awọn ti o kére ni ki iwọ ki o fi diẹ fun: ki a fi ilẹ-iní olukuluku fun u gẹgẹ bi iye awọn ti a kà ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Num 26

Wo Num 26:54 ni o tọ