Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 22:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni OLUWA là Balaamu li oju, o si ri angeli OLUWA duro loju ọ̀na, idà rẹ̀ fifàyọ si wà li ọwọ́ rẹ̀: o si tẹ̀ ori ba, o si doju rẹ̀ bolẹ.

Ka pipe ipin Num 22

Wo Num 22:31 ni o tọ