Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 22:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kẹtẹkẹtẹ na si wi fun Balaamu pe, Kẹtẹkẹtẹ rẹ ki emi ṣe, ti iwọ ti ngùn lati ìgba ti emi ti ṣe tirẹ titi di oni? emi a ha ma ṣe si ọ bẹ̃ rí? On si dahùn wipe, Ndao.

Ka pipe ipin Num 22

Wo Num 22:30 ni o tọ