Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 16:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olukuluku wọn si mú awo-turari rẹ̀, nwọn si fi iná sinu wọn, nwọn si fi turari lé ori wọn, nwọn si duro li ẹnu-ọ̀na agọ́ ajọ, pẹlu Mose ati Aaroni.

Ka pipe ipin Num 16

Wo Num 16:18 ni o tọ