Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 16:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki olukuluku wọn ki o mú awo-turari rẹ̀, ki ẹ si fi turari sinu wọn, ki olukuluku nyin ki o mú awo-turari rẹ̀ wá siwaju OLUWA, ãdọtalerugba awo-turari; iwọ pẹlu ati Aaroni, olukuluku awo-turari rẹ̀.

Ka pipe ipin Num 16

Wo Num 16:17 ni o tọ