Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 14:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. GBOGBO ijọ si gbé ohùn wọn soke, nwọn si ke: awọn enia na si sọkun li oru na.

2. Gbogbo awọn ọmọ Israeli si nkùn si Mose ati si Aaroni: gbogbo ijọ si wi fun wọn pe, Awa iba kuku ti kú ni ilẹ Egipti! tabi awa iba kú li aginjù yi!

Ka pipe ipin Num 14