Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 14:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ọmọ Israeli si nkùn si Mose ati si Aaroni: gbogbo ijọ si wi fun wọn pe, Awa iba kuku ti kú ni ilẹ Egipti! tabi awa iba kú li aginjù yi!

Ka pipe ipin Num 14

Wo Num 14:2 ni o tọ