Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 9:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ, ani iwọ nikanṣoṣo li Oluwa; iwọ li o ti dá ọrun, ọrun awọn ọrun pẹlu gbogbo ogun wọn, aiye, ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu rẹ̀, okun, ati ohun gbogbo ti mbẹ̀ ninu rẹ̀, iwọ si pa gbogbo wọn mọ́ lãyè, ogun ọrun si nsìn ọ.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:6 ni o tọ