Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 9:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Lefi, Jeṣua, Kadmieli, Bani, Haṣabaiah, Ṣerebiah, Hodijah, Sebaniah, ati Pelaniah, si wipe: Ẹ dide, ki ẹ fi iyìn fun Oluwa Ọlọrun nyin lai ati lailai: ibukun si ni fun orukọ rẹ ti o li ogo, ti o ga jù gbogbo ibukun ati iyìn lọ.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:5 ni o tọ