Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 9:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fun wọn li onjẹ lati ọrun wá fun ebi wọn, o si mu omi lati inu apata wá fun orungbẹ wọn, o si ṣe ileri fun wọn pe, ki nwọn lọ ijogun ilẹ na ti iwọ ti bura lati fi fun wọn.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:15 ni o tọ