Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 12:47 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo Israeli li ọjọ Serubbabeli, ati li ọjọ Nehemiah si fi ipin awọn akọrin, ati ti awọn adèna fun wọn olukuluku ni ipin tirẹ̀ li ojojumọ, nwọn si ya ohun mimọ́ awọn ọmọ Lefi si ọ̀tọ, awọn ọmọ Lefi si yà wọn si ọ̀tọ fun awọn ọmọ Aaroni.

Ka pipe ipin Neh 12

Wo Neh 12:47 ni o tọ