Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mal 1:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ifibu ni fun ẹlẹtàn na, ti o ni akọ ninu ọwọ́-ẹran rẹ̀, ti o si ṣe ileri ti o si fi ohun abùku rubọ si Oluwa; nitori Ọba nla li emi, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, ẹ̀ru si li orukọ mi lãrin awọn keferi.

Ka pipe ipin Mal 1

Wo Mal 1:14 ni o tọ