Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mal 1:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin wi pẹlu pe, Wo o agara kili eyi! ẹnyin ṣitìmú si i, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; ẹnyin si mu eyi ti o ya, ati arọ, ati olokunrùn wá; bayi li ẹnyin mu ọrẹ wá: emi o ha gbà eyi lọwọ nyin? li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Mal 1

Wo Mal 1:13 ni o tọ