Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 9:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si sọ fun Aaroni pe, Sunmọ pẹpẹ, ki o si ru ẹbọ ẹ̀ṣẹ rẹ, ati ẹbọ sisun rẹ, ki o si ṣètutu fun ara rẹ, ati fun awọn enia: ki o si ru ọrẹ-ẹbọ awọn enia, ki o si ṣètutu fun wọn; bi OLUWA ti fi aṣẹ lelẹ.

Ka pipe ipin Lef 9

Wo Lef 9:7 ni o tọ