Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati akọmalu kan ati àgbo kan fun ẹbọ alafia, lati fi ru ẹbọ niwaju OLUWA; ati ẹbọ ohunjijẹ ti a fi oróro pò: nitoripe li oni li OLUWA yio farahàn nyin.

Ka pipe ipin Lef 9

Wo Lef 9:4 ni o tọ