Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 9:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o si sọ fun awọn ọmọ Israeli pe, Ẹ mú obukọ kan wá fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ; ati ọmọ malu kan, ati ọdọ-agutan kan, mejeji ọlọdún kan, alailabùku, fun ẹbọ sisun;

Ka pipe ipin Lef 9

Wo Lef 9:3 ni o tọ