Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si múwa ninu ẹbọ alafia nì, ẹbọ ti a fi iná ṣe si OLUWA; ọrá rẹ̀, ati gbogbo ìru rẹ̀ ti o lọrá, on ni ki o mú kuro sunmọ egungun ẹhin; ati ọrá ti o bò ifun lori, ati gbogbo ọrá ti mbẹ lara ifun,

Ka pipe ipin Lef 3

Wo Lef 3:9 ni o tọ