Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 21:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki nwọn ki o si jasi mimọ́ fun Ọlọrun wọn, ki nwọn ki o má si ṣe bà orukọ Ọlọrun wọn jẹ́: nitoripe ẹbọ OLUWA ti a fi ina ṣe, ati àkara Ọlọrun wọn, ni nwọn fi nrubọ: nitorina ni ki nwọn ki o jẹ́ mimọ́.

Ka pipe ipin Lef 21

Wo Lef 21:6 ni o tọ