Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iwọ ba si mú ẹbọ ohunjijẹ akọ́so rẹ wá fun OLUWA, ki iwọ ki o si mú ṣiri ọkà daradara ti a yan lori iná wá fun ẹbọ ohunjijẹ akọ́so rẹ, ọkà gigún, ti ṣiri tutù.

Ka pipe ipin Lef 2

Wo Lef 2:14 ni o tọ