Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati gbogbo ọrẹ-ẹbọ ohunjijẹ rẹ ni ki iwọ ki o fi iyọ̀ dùn; bẹ̃ni iwọ kò gbọdọ jẹ ki iyọ̀ majẹmu Ọlọrun rẹ ki o má sí ninu ẹbọ ohunjijẹ rẹ: gbogbo ọrẹ-ẹbọ rẹ ni ki iwọ ki o fi iyọ̀ si.

Ka pipe ipin Lef 2

Wo Lef 2:13 ni o tọ