Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe ni ijọ́ keje, ni ki o fá gbogbo irun ori rẹ̀ kuro li ori rẹ̀, ati irungbọn rẹ̀, ati ipenpeju rẹ̀, ani gbogbo irun rẹ̀ ni ki o fá kuro: ki o si fọ̀ aṣọ rẹ̀, ki o si wẹ̀ ara rẹ̀ pẹlu ninu omi, on o si di mimọ́.

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:9 ni o tọ