Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ijọ́ kẹjọ ki o mú ọdọ-agutan meji akọ alailabùku wá, ati ọdọ-agutan kan abo ọlọdún kan alailabùku, ati idamẹwa mẹta òṣuwọn deali iyẹfun didara fun ẹbọ ohunjijẹ, ti a fi oróro pò, ati òṣuwọn logu oróro kan.

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:10 ni o tọ