Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:52 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si fi ẹ̀jẹ ẹiyẹ na wẹ̀ ile na mọ́, ati pẹlu omi ṣiṣàn nì, ati pẹlu ẹiyẹ alãye nì, ati pẹlu igi opepe nì, ati pẹlu ewe-hissopu nì, ati pẹlu ododó:

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:52 ni o tọ