Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:51 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si mú igi opepe, ati ewe-hissopu, ati ododó, ati ẹiyẹ alãye nì, ki o si tẹ̀ wọn bọ̀ inu ẹ̀jẹ ẹiyẹ ti a pa nì, ati ninu omi ṣiṣàn nì, ki o si fi wọ́n ile na nigba meje:

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:51 ni o tọ