Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ninu oróro iyokù ti mbẹ li ọwọ́ rẹ̀ ni ki alufa ki o fi si etí ọtún ẹniti a o wẹ̀numọ́, ati si àtampako ọwọ́ ọtún rẹ̀, ati si àtampako ẹsẹ̀ ọtún rẹ̀, lori ẹ̀jẹ ẹbọ ẹbi:

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:17 ni o tọ