Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 14:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o si tẹ̀ ika rẹ̀ ọtún bọ̀ inu oróro na ti mbẹ li ọwọ́ òsi rẹ̀, ki o si fi ika rẹ̀ ta ninu oróro na nigba meje niwaju OLUWA:

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:16 ni o tọ