Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 13:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni gbogbo ọjọ́ ti àrun na mbẹ li ara rẹ̀ ni ki o jẹ́ elẽri; alaimọ́ ni: on nikan ni ki o ma gbé; lẹhin ibudó ni ibujoko rẹ̀ yio gbé wà.

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:46 ni o tọ