Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 13:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati adẹ́tẹ na, li ara ẹniti àrun na gbé wà, ki o fà aṣọ rẹ̀ ya, ki o si fi ori rẹ̀ silẹ ni ìhoho, ki o si fi ìbo bò ète rẹ̀ òke, ki o si ma kepe, Alaimọ́, alaimọ́.

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:45 ni o tọ