Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joel 2:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ jẹ ki inu nyin dùn, ẹnyin ọmọ Sioni, ẹ si yọ̀ ninu Oluwa Ọlọrun nyin; nitoriti o ti fi akọrọ̀ ojò fun nyin bi o ti tọ́, on o si mu ki ojò rọ̀ silẹ fun nyin, akọrọ̀ ati arọ̀kuro ojò ni oṣù ikini.

Ka pipe ipin Joel 2

Wo Joel 2:23 ni o tọ